0% found this document useful (0 votes)
1K views

Iwe Ogun DR Eazy

Asiri ogun ibile

Uploaded by

Ahmed Isiak
Copyright
© © All Rights Reserved
Available Formats
Download as TXT, PDF, TXT or read online on Scribd
0% found this document useful (0 votes)
1K views

Iwe Ogun DR Eazy

Asiri ogun ibile

Uploaded by

Ahmed Isiak
Copyright
© © All Rights Reserved
Available Formats
Download as TXT, PDF, TXT or read online on Scribd
You are on page 1/ 2

ITUWO AWON AGBA TODAJU

Egbo lapalapa funfun ati pupa, epo obo ao lo Kuna daadaa, eso aworoso to po die, ao
lo oun naa Kuna daadaa, ao gun gbogbo awon nkan wonyi mo ose, ao fi eyin adie ibile
meta po ose yen, ao ko sinu igba tabi ike funfun, ao maa fiwe. NB: Ti a ba fe we
ose yii, ao maa diju nio, titi ti ao fi we tan, ti a ba ti fi omi sanra tan ni ao
laju wa. Ti a ba laju nigbati abanwe oju yoo maa fin wa.yoo bawa lara mu....

ELEYII NI AROBI ATUDE TODAJU


Egbo akerejupon tutu, Egbo túdè oojọ, Atajosi ẹyọ mẹwa, Ọṣẹ funfun, Awo sobi kan,
Ewe mowokuro, Iyo sibi kan. A o gun awon nkan wonyi papo ti yoo kunna dada, ti o ba
ti kunna tan, a o wa da iyo sibi kan na si, a o gun mo dada, leyin na a o wa gun mo
ose funfun na, leyin eyi a o wa fi omi gbigbona po ose na dada, a o wa ko ose na
sinu awo sobi olomori na, a o wa gbe si ibiti idi re koti ni kanle. A o ma bu ọṣẹ
na wẹ lalale pẹlu kainkan ibilẹ ki a … See more

OSE ITUWO AWON OTA ATI AGBA Aowa Isu ogiri sako,eru alamo,epo obo,ewe tude ati egbo
tude, ataijosin16, ao gun gbogbo re pomo ose dudu,lux,joy ao fi omi agbon po ose na
po ao mafi we laro-lale.
AKIYESI- PATAKI--ao fi epo pupa para kato we ose yio.

OGUN ITUWO AIYE TOGBONA JU (O TUN SISE FUNAGBELEPOTA)Iye agbe kan, iye aluko kan,
ikode kan, eye adan kan, eweoyo/ewedu lopolopo, odindi atare kan. A o ko gbogbo
awoneroja yen tele ape ijogun, ewe yen lomawa loke...leyin ti atijotan a o lo kuna
daada, a o ro sinu igo ff kan pamo.LILORE: A o ma bu diedie sori epo obo tofe to
atelewo, ao te nifa ejiogbe, a o pe ofore si. A o wa ta epo pupa lelori. A o fi
ahan latan. Bi o se ma lo niyen lalale ki a to sun...hmmm odaju pa,gbogbo ide
(bondage ara lo ma tu danu
OFORE! Atuluka loruko tan pe esu odara. Esu bamitu awon otamika. Baba dudu loruko
tan pe Orunmila. Sebi baba difatan, sebieyin agbalagba la n kesi. Ebami kesi baba
mi Agbonmiregunkowa tumi sile ninu igbekun osho, Aje, Alafa, woli, babaalawo etc…
Toripe bi adan badorikodo yogbon gbogbo epe tiwon badise danu ni, ewa bami gbon
gbogbo epe, ide aiyeburuku, airije, airimu, airina, airilo, wahala, idamu, ara
midanu loni, obo loni kin bo lowo osho, aje etc. a o tun seopolopo adua si. kai
Odaju.E lo dan wo ki e funle laboIFA EJI-OGBOTori awon miran ti won o mo bi o se
common to yi..0 00 00 00 0Iba Olodumare, iba agba, iba eyin ajunilo pata oo

ISEYI WA FUN OBINRIN TI KO GBORAN SI OKORELENU, TABI KI OBINRIN LE GBORAN SI


OKUNRINLENU KODA ALELO FUN KI O TO BERE WAHALARE, BE NA NI OBINRIN LE SE FUN
OKUNRIN,Ao wa ewe ogede agbagba die, ewe jokoje die, ao lopo maiyere tabi ata ijosi
die, ao fi se igbin odidi kan je, ao ge igbinyen si ona meje, awa oje eyokan tabi
meji nibe, obinrin na ojeeyokan tabi meji nibe, ao da iyoku si waju ita ile wa,
opari, tieyan barise, mofi olohun bura kosi bi obinrin na tile buru toolohun o ro
lokan kia, yio baramun ooo, ewe amo jeooo(olujide 1)

OGUN ISANGBESEAo waa iyo ati suger ao lo papo ao waa lo pelu Imi ojo ao pomo ose
dudu....Ao tee ose yen ni Ifa Ogunda ao maa se aduabi oba ti wuwa si, ao maa fi ose
yen we lararo ati alale

OWO MAGUNEja Ojiji kan 2. Kuluzo 9 3. Ewe apada 4. Odindi Ataare kanao jo papo, ao
sin gbere kan si ori Oko, ao fi Iyoku si gbeereyii ibadi yipo.. Ti magun ba wa lara
Obinrin oko wa ko ni lerara.

OGUN KI EJO OKA SO ENI TI O BA GBE OGUNBURUKU WA SI ORI ILE WA TABI ENU ONA
WA¤Odindi Egusi Bara kan ao wo Apa kan ninu egusi yii, ao loawon unkan wayii sinu
Bara yen 1. Ewe ina 2. Ewe Aragba 3.Egele dudu ao lo ao ko die tele Bara yen, ao
gbe Ori Oka Ojoole lori ao da iyoku ewe yen bo Ori Okaa yen, ao de pa ao fiOwu dudu
ati funfun di daadaa, ao ri mo ori Ile naa tabi enuona wa.

OOGUN IBON¤Ewe Tagiri Oojo ao gbo daadaa ao ni fi omi gbo o, omi ti ojade ni ara re
ao fi se Rice je ninu Ideri abo.. Odaju

OGUN IBON TODAJUAo wa igbe ewure ti o ti bi omo ri,,ao fi eyo atare kan si inuigbe
na, ao sa ti yio gbe kinse orun ,ao gbemi ni iwowo aosope boro boro ni ewure ya
igbe re,ti won ba yin ibon fun wayio tuka

ELE AKOYA ORI FIFOORI ...


EGUN AJA DIE - ORI EGUN OWAWA DIE - AOLO PAPO - AOFI TE IFA IRU EKUN-AO DA SINU EFE
OWU - AOFI OWU DUDU ATI FUNFUN WE -AOPE OHUN RE SI - AOWA GBE OKUTA LE MOLE -
WALAHI ORI YIO BEERE SINI FO ORI ELEDA TI APEORUKO RE SINU GBOLOHUN RE -
GBOLOHUN RE :-BI AJA BA GBO ORI AMA FO AJA - IWO L OMO L NI ORI FO BAYIO- BI OWAWA
BAKE - ORUN RE YIO WOLE - L OMO L IWO NI ORUN RE WOLE BAYIOOOO - AO WA GBE OKUTA LE
IKOBEERE NA LORI

You might also like